1 Corinthians 4:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn kan ti ń gbéraga bí ẹni pé n kò ní wá sọ́dọ̀ yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awọn ẹlomiran gberaga ninu nyin, bi ẹnipe emi kì yio tọ̀ nyin wá mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo mọ̀ pé àwọn mìíràn nínú yín tó ya onígbéraga ènìyàn, tí wọn ń rò pé ẹ̀rù ń bà ni láti wá sọ́dọ̀ yín láti ṣe ẹ̀tọ́ fún un yín.