1 Corinthians 5:13 — Compare Translations

2 translations compared side by side

Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awọn ti o wà lode li Ọlọrun nṣe idajọ wọn. Ẹ yọ enia buburu na kuro larin ara nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run nìkan ni onídájọ́ àwọn aláìgbàgbọ́. “Ẹ lé àwọn ènìyàn búburú náà kúrò láàrin yín.”