1 Corinthians 5:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dípò èyí tí ọkàn yín ìbá fi bàjẹ́, tí ẹ̀ bá sì yọ ẹni tí ń ṣe irú nǹkan bẹ́ẹ̀ kúrò láàrin yín, ẹ wá ń ṣe fáàrí!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin si nfẹ̀ soke, ẹnyin kò kuku kãnu ki a le mu ẹniti o hu iwa yi kuro larin nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin ń se ìgberaga, kí ni ṣe tí ojú kò tì yín, kí ẹ sì kún fún ìbànújẹ́, kí ẹ sì rí i pé ẹ yọ ọkùnrin náà tí ó hu ìwà yìí kúrò láàrin àwọn ọmọ ìjọ yín?