1 Corinthians 7:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí olukuluku wà ní ipò tí ó wà nígbà tí a pè é láti di onigbagbọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki olukuluku enia duro ninu ìpe nipasẹ eyi ti a ti pè e.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó yẹ kí ẹnìkọ̀ọ̀kan máa ṣe iṣẹ́ tí ó ń ṣe tẹ́lẹ̀, kí Ọlọ́run tó pé é sínú ìgbàgbọ́ nínú Kírísítì.