1 Corinthians 8:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ẹ ṣọ́ra kí òmìnira yín má di ohun tí yóo gbé àwọn aláìlera ṣubú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹ mã kiyesara ki omnira nyin yi ki o máṣe di ohun ikọsẹ fun awọn ti o ṣe ailera.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ẹ máa kíyèsí ara gidigidi nípa ìlò òmìnira yín kí ẹ má baà mú kí àwọn arákùnrin mìíràn tí í se onígbàgbọ́, tí ọkàn wọn ṣe aláìlera, subú sínú ẹ́sẹ̀.