1 Corinthians 9:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn mò ń fi ìyà jẹ ara mi, mò ń kó ara mi ní ìjánu. Ìdí ni pé nígbà tí mo bá ti waasu fún àwọn ẹlòmíràn tán, kí èmi alára má baà di ẹni tí kò ní yege ninu iré-ìje náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi npọn ara mi loju, mo si nmu u wá sabẹ itẹriba: pe lẹhin ti mo ti wasu fun awọn ẹlomiran, nitori ohunkohun, ki emi tikarami máṣe di ẹni itanù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n èmi ń ń kó ara mi níjànu, mo sì n mú un wá sí abẹ́ ìtẹríba, pé lẹ́yìn tí mo ti wàásù fún áwọn ẹlòmíràn, nítorí ohunkóhun, kí èmi fún rara mi má se di ẹni ìtanú fún ẹ̀bùn náà.