1 Kings 10:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Láti Ijipti ati Kue ni àwọn oníṣòwò Solomoni tií máa bá a ra àwọn ẹṣin wá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A si mu ẹṣin wá fun Solomoni lati Egipti li ọwọ́wọ, oniṣowo ọba nmu wọn wá fun owo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A sì mú ẹṣin wá fún Sólómónì láti Éjíbítì ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́, oníṣòwò ọba ni ó ń mú wọn wá fún òwe.