1 Kings 12:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Rehoboamu lọ sí Ṣekemu, nítorí pé gbogbo Israẹli ti péjọ níbẹ̀ láti fi jọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
REHOBOAMU si lọ si Ṣekemu, nitori gbogbo Israeli li o wá si Ṣekemu lati fi i jẹ ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Réhóbóámù sì lọ sí Ṣékémù, nítorí gbogbo Ísírẹ́lì ti lọ síbẹ̀ láti fi í jẹ ọba.