1 Kings 12:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti ìgbà náà ni Israẹli ti ń bá ìdílé Dafidi ṣọ̀tẹ̀ títí di òní yìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni Israeli ṣọtẹ̀ si ile Dafidi titi di oni yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni Ísírẹ́lì ṣọ̀tẹ̀ sí ilé Dáfídì títí di òní yìí.