1 Kings 12:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Jeroboamu ọmọ Nebati gbọ́ ìròyìn yìí ní Ijipti, (níbẹ̀ ni ó ń gbé láti ìgbà tí ó ti sá lọ fún Solomoni ọba), ó pada wá sílé láti Ijipti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, nigbati Jeroboamu, ọmọ Nebati, ti o wà ni Egipti sibẹ gbọ́, nitori ti o ti sá kuro niwaju Solomoni ọba, Jeroboamu si joko ni Egipti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Jéróbóámù ọmọ Nébátì, tí ó wà ní Éjíbítì síbẹ̀ gbọ́, nítorí tí ó ti sá kúrò níwájú Sólómónì ọba, ó sì wà ní Éjíbítì.