1 Kings 12:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
pé kí ó jíṣẹ́ fún Rehoboamu, ọba Juda ati gbogbo ẹ̀yà Juda ati ti Bẹnjamini,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sọ fun Rehoboamu, ọmọ Solomoni, ọba Juda, ati fun gbogbo ile Juda ati Benjamini, ati fun iyokù awọn enia wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Sọ fún Réhóbóámù, ọmọ Sólómónì, ọba Júdà àti fún gbogbo ilé Júdà àti ti Bẹ́ńjámínì, àti fún àwọn ènìyàn tó kù wí pé,