1 Kings 12:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí ó yá, ó rò ninu ara rẹ̀ pé, “Ìjọba yìí yóo pada di ti ilé Dafidi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jeroboamu si wi li ọkàn rẹ̀ pe, Nisisiyi ni ijọba na yio pada si ile Dafidi:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jéróbóámù rò nínú ara rẹ̀ pé, “Ìjọba náà yóò padà nísinsìnyìí sí ilé Dáfídì.