1 Kings 12:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli ranṣẹ pè é, òun ati gbogbo wọ́n sì tọ Rehoboamu lọ, wọ́n wí fún un pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si ranṣẹ pè e, ati Jeroboamu ati gbogbo ijọ Israeli wá, nwọn si sọ fun Rehoboamu wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ránṣẹ́ sí Jéróbóámù, òun àti gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì sì lọ sọ́dọ̀ Réhóbóámù, wọ́n sì wí fún un pé: