1 Kings 13:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wolii ará Juda yìí bá bá wolii àgbàlagbà náà pada lọ sí ilé rẹ̀, ó sì jẹun níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ li o si ba a pada lọ, o si jẹ onjẹ ni ile rẹ̀, o si mu omi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni ènìyàn Ọlọ́run náà sì padà pẹ̀lú rẹ̀, ó sì jẹ oúnjẹ ó sì mu omi ní ilé rẹ̀.