1 Kings 13:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n jẹun tan, wolii àgbàlagbà yìí di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan ní gàárì fún wolii ará Juda.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, lẹhin igbati o ti jẹ onjẹ, ati lẹhin igbati o ti mu, li o di kẹtẹkẹtẹ ni gari fun u, eyini ni, fun woli ti o ti mu pada bọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ènìyàn Ọlọ́run sì ti jẹun tán àti mu omi tan, wòlíì tí ó ti mú u padà sì di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ní gàárì fún un.