1 Kings 13:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọkunrin kan tí wọn ń kọjá lọ rí òkú ọkunrin yìí lójú ọ̀nà, ati kinniun tí ó dúró tì í. Wọ́n lọ sí ìlú Bẹtẹli níbi tí wolii àgbàlagbà náà ń gbé, wọ́n sì ròyìn ohun tí wọ́n rí fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si kiyesi i, awọn enia nkọja, nwọn ri pe, a gbe okú na sọ si oju ọ̀na, kiniun na si duro tì okú na: nwọn si wá, nwọn si sọ ọ ni ilu ti woli àgba na ngbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn tí ó ń kọjá sì rí òkú náà, wọ́n sì lọ, wọ́n sì sọ ọ́ ní ìlú tí wòlíì àgbà náà ń gbé.