1 Kings 13:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wolii àgbàlagbà yìí gbé òkú ọkunrin náà sí ẹ̀yìn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ ó sì gbé e pada wá sí ìlú Bẹtẹli láti ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, ati láti sin ín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Woli na mu okú enia Ọlọrun na, o si gbé e lori kẹtẹkẹtẹ na, o si mu u pada bọ̀: woli àgba na si wá si ilu, lati ṣọ̀fọ, ati lati sin i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wòlíì náà gbé òkú ènìyàn Ọlọ́run náà, ó sì gbé e lé orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ó sì gbé e padà wá sí ìlú ara rẹ̀ láti ṣọ̀fọ̀ fún un àti láti sin ín.