1 Kings 13:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ninu ibojì tirẹ̀ gan-an ni ó sin ín sí. Òun ati àwọn ọmọ rẹ̀ sì ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, ó ní, “Ó ṣe, arakunrin mi! Arakunrin mi!”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si tẹ okú rẹ̀ sinu iboji ara rẹ̀: nwọn si sọ̀fọ lori rẹ̀, pe: O ṣe, arakunrin mi!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó gbé òkú náà sínú ibojì ara rẹ̀, wọ́n sì ṣọ̀fọ̀ lórí rẹ̀, wọ́n sì wí pé, “Ó ṣe, arákùnrin mi!”