1 Kings 13:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ní, “Nítòótọ́, ọ̀rọ̀ ìbáwí tí OLUWA pàṣẹ pé kí ó sọ sí pẹpẹ Bẹtẹli, ati gbogbo pẹpẹ ìrúbọ tí ó wà káàkiri ní àwọn ìlú Samaria yóo ṣẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ni ṣiṣẹ, ọ̀rọ ti o kigbe nipa ọ̀rọ Oluwa si pẹpẹ na ni Beteli, ati si gbogbo ile ibi giga ti mbẹ ni gbogbo ilu Samaria, yio ṣẹ dandan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí iṣẹ́ tí ó jẹ́ nípa ọ̀rọ̀ OLÚWA sí pẹpẹ tí ó wà ní Bétélì àti sí gbogbo ojúbọ lórí ibi gíga tí ń bẹ ní àwọn ìlú Samáríà yóò wá sí ìmúṣẹ dájúdájú.”