1 Kings 13:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀ṣẹ̀ ni ohun tí ó ṣe yìí, ẹ̀ṣẹ̀ yìí ni ó sì run ìran rẹ̀ lórí oyè, tí wọ́n fi parun patapata lórílẹ̀ ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nkan yi si di ẹ̀ṣẹ ile Jeroboamu, ani lati ke e kuro, ati lati pa a run kuro lori ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí sì ni ẹ̀ṣẹ̀ ilé Jéróbóámù, èyí tí ó yọrí sí ìṣubú rẹ̀, a sì pa á run kúrò lórí ilẹ̀.