1 Kings 14:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní àkókò yìí Abija, ọmọ Jeroboamu ọba ṣàìsàn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li àkoko na, Abijah ọmọ Jeroboamu ṣàisan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní àkókò náà Ábíjà ọmọ Jéróbóámù sì ṣàìsàn,