1 Kings 16:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ahabu ọmọ Omiri ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA ju gbogbo àwọn tí wọ́n ṣáájú rẹ̀ lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ahabu, ọmọ Omri, si ṣe buburu li oju Oluwa jù gbogbo awọn ti o wà ṣaju rẹ̀ lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áhábù ọmọ Ómírì sì ṣe búburú ní ojú OLÚWA ju gbogbo àwọn tí ó wà ṣáájú rẹ̀ lọ.