1 Kings 17:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Obinrin yìí bá lọ, ó ṣe bí Elija ti wí. Òun ati Elija ati gbogbo ará ilé rẹ̀ sì ń jẹ àjẹyó fún ọpọlọpọ ọjọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si lọ, o ṣe gẹgẹ bi ọ̀rọ Elijah: ati on ati obinrin na, ati ile rẹ̀ jẹ li ọjọ pupọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì lọ, ó sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Èlíjà ti sọ fún un. Oúnjẹ sì wà fún Èlíjà àti obìnrin náà àti ilé rẹ̀ ní ojoojúmọ́.