1 Kings 18:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Omi náà ṣàn sílẹ̀ yí pẹpẹ ká, ó sì kún kòtò tí wọ́n gbẹ́ yípo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Omi na si ṣàn yi pẹpẹ na ka, o si fi omi kún kòtò na pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Omi náà sì ṣàn yí pẹpẹ náà ká, ó sì fi omi kún yàrà náà pẹ̀lú.