1 Kings 2:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kò pẹ́ pupọ lẹ́yìn náà, Dafidi, ọba kú, wọ́n sì sin ín sí ìlú Dafidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i ni ilu Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Dáfídì sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín ní ìlú Dáfídì.