1 Kings 21:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ti Jesebẹli, OLUWA ní, ajá ni yóo jẹ òkú rẹ̀ láàrin ìlú Jesireeli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati niti Jesebeli pẹlu Oluwa sọ wipe, Awọn ajá yio jẹ Jesebeli ninu yàra Jesreeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Àti níti Jésébélì pẹ̀lú OLÚWA wí pé: ‘Àwọn ajá yóò jẹ Jésébélì nínú yàrá Jésírẹ́lì.’