1 Kings 21:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Naboti dáhùn pé, “Ọwọ́ àwọn baba ńlá mi ni mo ti jogún ọgbà àjàrà yìí; OLUWA má jẹ́ kí n rí ohun tí n óo fi gbé e fún ọ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Naboti si wi fun Ahabu pe, Oluwa má jẹ ki emi fi ogún awọn baba mi fun ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Nábótì wí fún Áhábù pé, “OLÚWA má jẹ́ kí èmi fi ogún àwọn bàbá mi fún ọ.”