1 Kings 22:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mikaaya bá dá a lóhùn pé, “O óo rí i nígbà tí ó bá di ọjọ́ náà, tí o bá sá wọ yàrá inú patapata lọ, láti fi ara pamọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mikaiah si wipe, Kiyesi i, iwọ o ri i li ọjọ na, nigbati iwọ o lọ lati inu iyẹwu de iyẹwu lati fi ara rẹ pamọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Míkáyà sì wí pé, “Ìwọ yóò rí i ní ọjọ́ náà, nígbà tí ìwọ yóò lọ láti inú ìyẹ̀wù dé ìyẹ̀wù láti fi ara rẹ pamọ́.”