1 Kings 4:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Orúkọ àwọn olórí ninu àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ nìwọ̀nyí: Asaraya, ọmọ Sadoku ni alufaa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn wọnyi ni awọn ijoye ti o ni; Asariah, ọmọ Sadoku alufa,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè rẹ̀: Ásáríyà ọmọ Ṣádókù àlùfáà: