1 Kings 4:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Elihorefi ati Ahija, meji ninu àwọn ọmọ Ṣiṣa ni akọ̀wé ní ààfin ọba. Jehoṣafati, ọmọ Ahiludi ni olùtọ́jú àwọn ìwé àkọsílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Elihorefu ati Ahiah, awọn ọmọ Ṣiṣa li akọwe, Jehoṣafati ọmọ Ahiludi li akọwe ilu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Élíhóréfù àti Áhíjà àwọn ọmọ Ṣísánì akọ̀wé; Jèhósáfátì ọmọ Áhílúdì ni akọ̀wé ìlú;