1 Kings 4:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ahiṣari ni olùdarí gbogbo àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ninu ààfin. Adoniramu ọmọ Abida ni olórí àwọn tí ń kó àwọn eniyan ṣiṣẹ́ tipátipá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Ahiṣari li o ṣe olori agbo-ile: ati Adoniramu, ọmọ Abda li o nṣe olori iṣẹ-irú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áhísárì ni olùtọ́jú ààfin; Ádónírámù ọmọ Ábídà ni ó ń ṣe olórí iṣẹ́-ìlú