1 Kings 6:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
wọ́n sì yọ́ wúrà bo ilẹ̀ àwọn yàrá náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ ile na li o fi wura tẹ́ ninu ati lode.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì tún fi wúrà tẹ́ ilẹ̀ ilé náà nínú àti lóde.