1 Kings 6:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu oṣù Sifi, ní ọdún kẹrin ìjọba Solomoni, ni wọ́n fi ìpìlẹ̀ ilé ìsìn náà sọlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọdun kẹrin li a fi ipilẹ ile Oluwa le ilẹ̀, li oṣu Sifi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọdún kẹrin ni a fi ìpìlẹ̀ ilé OLÚWA lé ilẹ̀, ní oṣù Sífì.