1 Kings 7:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọdún mẹtala ni Solomoni fi parí kíkọ́ ilé ti ara rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ṢUGBỌN Solomoni fi ọdun mẹtala kọ́ ile on tikararẹ̀, o si pari gbogbo iṣẹ ile rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sólómónì sì lo ọdún mẹ́talá láti fi kọ́ ààfin rẹ̀, ó sì parí gbogbo iṣẹ́ ààfin rẹ̀.