1 Kings 7:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Iṣẹ́ ọnà ìtànná lílì ni wọ́n ṣe sára àwọn òpó náà. Bẹ́ẹ̀ ni iṣẹ́ ṣe parí lórí àwọn òpó náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lori oke awọn ọwọ̀n na ni iṣẹ lili wà; bẽni iṣẹ ti awọn ọwọ̀n si pari.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìparí lókè sì jẹ́ àwòrán lílì. Bẹ́ẹ̀ ni iṣẹ́ ti àwọn ọ̀wọ̀n sì parí.