1 Kings 7:48 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Solomoni ṣe gbogbo àwọn ohun èlò wọnyi sinu ilé OLUWA: pẹpẹ wúrà, tabili wúrà fún burẹdi ìfihàn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Solomoni si ṣe gbogbo ohun-elo ti iṣe ti ile Oluwa: pẹpẹ wura, ati tabili wura, lori eyi ti akara ifihan gbe wà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sólómónì sì tún ṣe gbogbo ohun ọ̀ṣọ́ tí ń ṣe ti ilé OLÚWA pẹ̀lú: pẹpẹ wúrà; tabílì wúrà lórí èyí tí àkàrà ìfihàn gbé wà;