1 Kings 7:49 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn ọ̀pá fìtílà tí wọ́n fi ojúlówó wúrà ṣe: marun-un ní ìhà àríwá, ati marun-un ní ìhà gúsù níwájú Ibi-Mímọ́-Jùlọ; àwọn òdòdó, àwọn fìtílà, ati àwọn ẹ̀mú wúrà,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ọpa fitila wura daradara, marun li apa ọtún ati marun li apa òsi, niwaju ibi mimọ́-julọ, pẹlu itanna eweko, ati fitila, ati ẹ̀mú wura.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀pá fìtílà kìkì wúrà, márùn-ún ní apá ọ̀tún àti márùn ún ní apá òsì, níwájú ibi mímọ́ jùlọ; ìtànná ewéko; fìtílà àti ẹ̀mú wúrà;