1 Kings 8:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Solomoni bá gbadura, ó ní, “OLUWA, ìwọ ni o fi oòrùn sí ojú ọ̀run, ṣugbọn sibẹsibẹ o yàn láti gbé inú ìkùukùu ati òkùnkùn biribiri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Solomoni sọ pe: Oluwa ti wi pe, on o mã gbe inu okùnkun biribiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Sólómónì sì wí pé, “OLÚWA ti wí pé, òun yóò máa gbé inú òkùnkùn biribiri;