1 Kings 8:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn tí gbogbo àwọn àgbààgbà ti péjọ, àwọn alufaa gbé Àpótí Ẹ̀rí náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn agbàgba Israeli si wá, awọn alufa si gbe apoti-ẹri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí gbogbo àwọn àgbà Ísírẹ́lì dé, àwọn àlùfáà sì gbé àpótí-ẹ̀rí,