1 Kings 8:54 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà ti Solomoni parí adura ati ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ sí OLUWA, ó dìde kúrò níwájú pẹpẹ níbi tí ó kúnlẹ̀ sí, tí ó sì gbé ọwọ́ sókè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, bi Solomoni ti pari gbigbà gbogbo adura ati ẹ̀bẹ yi si Oluwa, o dide kuro lori ikunlẹ ni ẽkún rẹ̀ niwaju pẹpẹ Oluwa pẹlu titẹ́ ọwọ rẹ̀ si oke ọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Sólómónì ti parí gbogbo àdúrà àti ẹ̀bẹ̀ yìí sí OLÚWA tán, ó dìde kúrò lórí eékún rẹ̀ níwájú pẹpẹ OLÚWA níbi tí ó ti kúnlẹ̀ tí ó sì na ọwọ́ rẹ̀ sí òkè ọ̀run