1 Kings 8:60 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé lè mọ̀ pé OLUWA ni Ọlọrun, ati pé kò sí ẹlòmíràn mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki gbogbo enia aiye le mọ̀ pe, Oluwa on li Ọlọrun, kò si ẹlomiran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
kí gbogbo ènìyàn ayé lè mọ̀ pé OLÚWA òun ni Ọlọ́run, kò sì sí ẹlòmíràn.