1 Kings 9:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà ni Solomoni ṣe tún ìlú náà kọ́.) Pẹlu apá ìsàlẹ̀ Beti Horoni,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Solomoni si kọ́ Geseri, ati Bethoroni-isalẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sólómónì sì tún Gésérì kọ́, àti Bẹti Hórónì ìṣàlẹ̀,