1 Samuel 1:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn tí wọ́n ti pa akọ mààlúù náà tán, wọ́n mú Samuẹli tọ Eli lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn pa ẹgbọrọ malu, nwọn si mu ọmọ na tọ̀ Eli wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n pa ẹgbọrọ màlúù, wọ́n sì mú ọmọ náà tọ Élì wá.