1 Samuel 1:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, mo wá ya ọmọ náà sọ́tọ̀ fún OLUWA, ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ yóo jẹ́ ti OLUWA.” Lẹ́yìn náà, wọ́n sin OLUWA níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina pẹlu emi fi i fun Oluwa; ni gbogbo ọjọ aiye rẹ̀: nitoriti mo ti bere rẹ̀ fun Oluwa. Nwọn si wolẹ-sin Oluwa nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà pẹ̀lú, èmi fí i fún OLÚWA; ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀: nítorí tí mo ti béèrè rẹ̀ fún OLÚWA.” Wọn si wólẹ̀ sin OLÚWA nibẹ̀.