1 Samuel 10:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Samuẹli pe àwọn eniyan náà jọ siwaju OLUWA ní Misipa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Samueli si pe gbogbo enia jọ siwaju Oluwa ni Mispe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sámúẹ́lì pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jọ sí iwájú OLÚWA ní Mísípà.