1 Samuel 10:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni, Samuẹli mú kí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan tò kọjá níwájú OLUWA, gègé sì mú ẹ̀yà Bẹnjamini.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Samueli si mu ki gbogbo ẹya Israeli sunmọ tosi, a si mu ẹya Benjamini.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà Sámúẹ́lì mú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì súnmọ́ tòsí, ó yan ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì.