1 Samuel 10:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n bi OLUWA pé, “Àbí ọkunrin náà kò wá ni?” OLUWA dá wọn lóhùn pé, “Ó ti farapamọ́ sí ààrin àwọn ẹrù.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina nwọn si tun bere lọdọ Oluwa sibẹ bi ọkunrin na yio wá ibẹ̀. Oluwa si dahùn wipe, Wõ, o pa ara rẹ̀ mọ lãrin ohun-elò.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe ìwádìí lọ́wọ́ OLÚWA pé, “Ṣé ọkùnrin náà ti wá sí bí ni?” OLÚWA sì sọ pé, “Bẹ́ẹ̀ ni ó ti fi ara rẹ̀ pamọ́ láàrin àwọn ẹrù.”