1 Samuel 11:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli bá bèèrè lọ́wọ́ Samuẹli pé, “Níbo ni àwọn tí wọ́n sọ pé kò yẹ kí Saulu jẹ ọba wa wà? Ẹ kó wọn jáde, kí á pa wọ́n.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia na si wi fun Samueli, pe, Tani wipe, Saulu yio ha jọba lori wa? mu awọn ọkunrin na wá, a o si pa wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn sọ fún Sámúẹ́lì pé, “Ta ni ó béèrè wí pé, Ṣọ́ọ̀lù yóò ha jọba lórí wa? Mú àwọn ọkùnrin náà wá, a ó sì pa wọ́n.”