1 Samuel 11:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn Saulu dá wọn lóhùn pé, “A kò ní pa ẹnikẹ́ni lónìí, nítorí pé, òní ni ọjọ́ tí OLUWA gba Israẹli là.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Saulu si wi pe, a kì yio pa ẹnikẹni loni yi; nitoripe loni li Oluwa ṣiṣẹ igbala ni Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ṣọ́ọ̀lù wí pé, “A kì yóò pa ẹnikẹ́ni lónìí, nítorí lónìí yìí ni OLÚWA gba Ísírẹ́lì là.”