1 Samuel 11:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Samuẹli wí fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí á lọ sí Giligali, kí á lè túbọ̀ fi ìdí ìjọba Saulu múlẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Samueli wi fun awọn enia na pe, Wá, ki a lọ si Gilgali, ki a le tun ijọba na ṣe nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Sámúẹ́lì wí fún àwọn ènìyàn pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a lọ sí Gílígálì, kí a lè fi ẹṣẹ̀ Ṣọ́ọ̀lù múlẹ̀ bí ọba.”